Jeremáyà 10:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àgọ́ mi bàjẹ́, gbogbo okùn rẹ̀ sì já.Àwọn ọmọ mi ti lọ lọ́dọ̀ mi, wọn kò sì sí mọ́Kò sí ẹnìkankan pẹ̀lú mi mọ́, báyìí kò sí ẹni tí yóòná àgọ́ mi tàbí ṣe ibùgbé fún mi

Jeremáyà 10

Jeremáyà 10:10-25