Jeremáyà 10:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ohun tí Olúwa wí:“Má se tọ ọ̀nà àwọn orílẹ̀ èdètàbí kí ẹ jẹ́ kí àmù òfuurufú dààmúyín, nítorí pé wọ́n ń dààmú orílẹ̀ èdè.

Jeremáyà 10

Jeremáyà 10:1-11