Nítorí èyí ni Olúwa wí:“Ní àkókò yìí,èmi yóò gbọn àwọn tí ó ń gbéilẹ̀ náà jáde. Èmi yóò mú ìpọ́njúbá wọn, kí wọn kí ó lè rí wọn mú.”