Jeremáyà 10:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Sọ èyí fún wọn: ‘Àwọn ọlọ́run kékèèké tí kò dá ọ̀run àti ayé ni yóò ṣègbé láti ayé àti ní abẹ́ ọ̀run.’ ”

Jeremáyà 10

Jeremáyà 10:6-18