Jeremáyà 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó tó di pé mo dá ọ láti inú ni mo ti mọ̀ ọ́,kí ó sì tó di pé a bí ọ ni mo ti yà ọ́ sọ́tọ̀.Mo yàn ọ́ gẹ́gẹ́ bí wòlíì fún àwọn orílẹ̀ èdè.

Jeremáyà 1

Jeremáyà 1:1-10