Jeremáyà 1:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wà ní ìmúrasílẹ̀! Dìde dúró kí o sì sọ fún wọn ohunkóhun tí mo bá pa lásẹ fún wọn. Má ṣe jẹ́ kí wọn dẹ́rù bà ọ́, èmi yóò sì sọ ọ́ di ẹ̀rù níwájú wọn.

Jeremáyà 1

Jeremáyà 1:16-19