Jẹ́nẹ́sísì 9:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ó jẹ ẹnikẹ́ni tó bá ta ẹ̀jẹ̀ (gba ẹ̀mí) ènìyàn sílẹ̀ níyà. Ikú ni yóò jẹ́ ìjìyà ìpànìyàn, ìbá à ṣe láti ọwọ́ ẹranko tàbí ènìyàn.

Jẹ́nẹ́sísì 9

Jẹ́nẹ́sísì 9:4-6