Jẹ́nẹ́sísì 9:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wí pé:“Ègún ni fún Kénánì.Ìránṣẹ́ àwọn ìránṣẹ́ ni yóò máaṣe fún àwọn arákùnrin rẹ̀.”

Jẹ́nẹ́sísì 9

Jẹ́nẹ́sísì 9:15-28