Jẹ́nẹ́sísì 9:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ámù tí í ṣe baba Kénání sì rí baba rẹ̀ ní ìhòòhò bẹ́ẹ̀ ni ó sì lọ sọ fún àwọn arákùnrin rẹ̀ méjèèjì ní ìta.

Jẹ́nẹ́sísì 9

Jẹ́nẹ́sísì 9:12-29