Jẹ́nẹ́sísì 9:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbàkígbà tí òsùmàrè bá yọ ní ojú ọ̀run, èmi yóò rí i, èmi yóò sì rántí májẹ̀mú ayérayé tí ń bẹ láàrin Ọlọ́run àti gbogbo ẹ̀dá alààyè tí ń bẹ ní ayé.”

Jẹ́nẹ́sísì 9

Jẹ́nẹ́sísì 9:13-20