Jẹ́nẹ́sísì 9:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ti fi òṣùmàrè sí ojú ọ̀run, yóò sì jẹ́ àmì májẹ̀mú láàrin èmi àti ayé.

Jẹ́nẹ́sísì 9

Jẹ́nẹ́sísì 9:6-14