Jẹ́nẹ́sísì 9:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti pẹ̀lú gbogbo ẹ̀dá alààyè tí ó wà pẹ̀lú yín, ìbáà ṣe ẹja, ẹran ọ̀sìn, ẹranko igbó, gbogbo ohun tí ó jáde kúrò nínú ọkọ̀ pẹ̀lú yín, àní gbogbo ẹ̀dá alààyè ní ayé.

Jẹ́nẹ́sísì 9

Jẹ́nẹ́sísì 9:6-19