Jẹ́nẹ́sísì 8:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì rán ẹyẹ ìwò kan jáde, tí ó ń fò káàkiri síwá àti ṣẹ́yìn títí omi fi gbẹ kúrò ní orí ilẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 8

Jẹ́nẹ́sísì 8:3-12