Jẹ́nẹ́sísì 8:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Omi náà sì ń gbẹ si títí di oṣù kẹwàá. Ní ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù kẹ́wàá, orí àwọn òkè sì farahàn.

Jẹ́nẹ́sísì 8

Jẹ́nẹ́sísì 8:1-7