Jẹ́nẹ́sísì 8:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nóà sì mọ pẹpẹ fún Olúwa, ó sì mú lára àwọn ẹran tí ó mọ́ àti ẹyẹ tí ó mọ́, ó sì fi rúbọ ṣísun lórí pẹpẹ.

Jẹ́nẹ́sísì 8

Jẹ́nẹ́sísì 8:14-22