Jẹ́nẹ́sísì 8:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nóà tún mú sùúrù fún ọjọ́ méje, ó sì tún rán àdàbà náà jáde, ṣùgbọ́n àdàbà náà kò padà sọ́dọ̀ rẹ̀ mọ́.

Jẹ́nẹ́sísì 8

Jẹ́nẹ́sísì 8:3-18