Jẹ́nẹ́sísì 8:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì dúró fún ọjọ́ méje sí i; ó sì tún rán àdàbà náà jáde láti inú ọkọ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 8

Jẹ́nẹ́sísì 8:2-19