Jẹ́nẹ́sísì 7:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Méjìméjì ni àwọn ẹran tí ó jẹ́ mímọ́ àti aláìmọ́, ti ẹyẹ àti ti gbogbo àwọn ẹ̀dá afàyàfà,

Jẹ́nẹ́sísì 7

Jẹ́nẹ́sísì 7:6-13