Jẹ́nẹ́sísì 6:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mú onírúurú àwọn ẹyẹ, ẹranko àti àwọn ohun tí ń rákò ní méjìméjì kí a bá lè pa wọ́n mọ́ láàyè.

Jẹ́nẹ́sísì 6

Jẹ́nẹ́sísì 6:10-22