Jẹ́nẹ́sísì 6:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run sì rí bí ayé ti bàjẹ́ tó, nítorí àwọn ènìyàn ayé ti bá ara wọn jẹ́ ní gbogbo ọ̀nà wọn.

Jẹ́nẹ́sísì 6

Jẹ́nẹ́sísì 6:6-19