Jẹ́nẹ́sísì 50:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ni Jósẹ́fù gòkè lọ láti sìnkú baba rẹ̀. Gbogbo àwọn ìjòyè Fáráò ni ó sìn ín lọ—àwọn ènìyàn pàtàkì pàtàkì ilé rẹ̀, àti àwọn ènìyàn pàtàkì pàtàkì ilẹ̀ Éjíbítì.

Jẹ́nẹ́sísì 50

Jẹ́nẹ́sísì 50:5-8