Jẹ́nẹ́sísì 50:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósẹ́fù sì ń gbé ní Éjíbítì pẹ̀lú gbogbo ìdílé baba rẹ̀. Ó sì wà láàyè fún àádọ́fà (110) ọdún.

Jẹ́nẹ́sísì 50

Jẹ́nẹ́sísì 50:19-26