Jẹ́nẹ́sísì 50:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósẹ́fù sì subú lé baba rẹ̀, ó sunkún, ó sì fẹnu kò ó ní ẹnu.

Jẹ́nẹ́sísì 50

Jẹ́nẹ́sísì 50:1-9