Jẹ́nẹ́sísì 49:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bẹ́ńjámínì jẹ́ ìkookò tí ó burú.Ní òwúrọ̀ ni ó jẹ ẹran-ọdẹ rẹ,ní àsáálẹ́, ó pín ìkógun.”

Jẹ́nẹ́sísì 49

Jẹ́nẹ́sísì 49:25-31