Jẹ́nẹ́sísì 48:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósẹ́fù fún baba rẹ̀ lésì pé, “Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin tí Ọlọ́run ti fi fún mi ní ìhín.”Nígbà náà ni Ísírẹ́lì wí pé, “Kó wọn wá sí ọ̀dọ̀ mi kí èmi kí ó baà le súre fún wọn.”

Jẹ́nẹ́sísì 48

Jẹ́nẹ́sísì 48:5-17