Jẹ́nẹ́sísì 48:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jákọ́bù wí fún Jósẹ́fù pé, “Ọlọ́run Olódùmarè fara hàn mí ní Lúsì ní ilẹ̀ Kénánì, níbẹ̀ ni ó sì ti súre fún mi.

Jẹ́nẹ́sísì 48

Jẹ́nẹ́sísì 48:2-6