Jẹ́nẹ́sísì 48:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Jósẹ́fù kó àwọn ọmọ náà kúrò ní orí eékún baba rẹ̀, ó wólẹ̀, ó sì tẹ́ríba.

Jẹ́nẹ́sísì 48

Jẹ́nẹ́sísì 48:4-18