Jẹ́nẹ́sísì 46:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin tí Rákẹ́lì bí fún Jákọ́bù. Wọ́n jẹ́ mẹ́rìnlá (14) lápapọ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 46

Jẹ́nẹ́sísì 46:18-31