Jẹ́nẹ́sísì 46:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní Éjíbiti, Áṣénátù ọmọbìnrin Pọ́tíférà, alábojútó àti àlùfáà Ónì, bí Mánásè àti Éfúráímù fún Jósẹ́fù.

Jẹ́nẹ́sísì 46

Jẹ́nẹ́sísì 46:14-26