Jẹ́nẹ́sísì 45:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn wí fún un pé, “Jósẹ́fù sì wà láàyè! Kódà òun ni alákòóṣo ilẹ̀ Éjíbítì” Ẹnu ya Jákọ́bù, kò sì gbà wọ́n gbọ́

Jẹ́nẹ́sísì 45

Jẹ́nẹ́sísì 45:25-28