Jẹ́nẹ́sísì 45:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó fún ẹni kọ̀ọ̀kan wọn ní aṣọ tuntun. Ṣùgbọ́n Bẹ́ńjámínì ni ó fún ní ọ̀ọ́dúnrún ẹyọ owó (300) idẹ fàdákà àti ìpààrọ̀ aṣọ márùn ún.

Jẹ́nẹ́sísì 45

Jẹ́nẹ́sísì 45:13-25