Jẹ́nẹ́sísì 45:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“A pàṣẹ fún ọ láti sọ fún wọn pé, ‘Ẹ ṣe èyí: Ẹ mú kẹ̀kẹ́ ẹrù láti ilẹ̀ Éjíbítì fún àwọn ọmọ yín àti àwọn aya yín. Kí ẹ sì mú baba yín tọ mí wá.

Jẹ́nẹ́sísì 45

Jẹ́nẹ́sísì 45:9-28