Jẹ́nẹ́sísì 45:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ìròyìn náà dé ààfin Fáráò pé àwọn arákùnrin Jósẹ́fù dé, inú Fáráò àti àwọn ìjòyè rẹ̀ dùn.

Jẹ́nẹ́sísì 45

Jẹ́nẹ́sísì 45:10-26