Jẹ́nẹ́sísì 44:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A tilẹ̀ mú owó tí a rí lẹ́nu àpò wa padà tọ̀ ọ́ wá láti ilẹ̀ Kénánì. Nítorí náà èéṣe tí àwa yóò fi jí wúrà tàbí idẹ ní ilé olúwa à rẹ?

Jẹ́nẹ́sísì 44

Jẹ́nẹ́sísì 44:3-12