Jẹ́nẹ́sísì 44:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Baba mi, ìránṣẹ́ rẹ wí fún wa pé, ‘Ẹ mọ̀ pé ìyàwó mi bí ọmọkùnrin méjì fún mi.

Jẹ́nẹ́sísì 44

Jẹ́nẹ́sísì 44:23-28