Jẹ́nẹ́sísì 44:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósẹ́fù sì wà nínú ilé nígbà tí Júdà àti àwọn arákùnrin rẹ̀ wọlé wá. Gbogbo wọn sì wólẹ̀ níwájú rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 44

Jẹ́nẹ́sísì 44:13-15