Jẹ́nẹ́sísì 44:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúkúlùkù wọn yára sọ àpò rẹ̀ kalẹ̀, wọ́n sì tú u.

Jẹ́nẹ́sísì 44

Jẹ́nẹ́sísì 44:8-13