Jẹ́nẹ́sísì 43:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ísírẹ́lì béèrè pé, “Èéṣe tí ẹ fi kó ìdààmú yìí bá mi nípa sísọ fún ọkùnrin náà wí pé ẹ ní arákùnrin mìíràn?”

Jẹ́nẹ́sísì 43

Jẹ́nẹ́sísì 43:1-11