Jẹ́nẹ́sísì 43:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ìwọ yóò bá rán Bẹ́ńjámínì arákùnrin wa lọ pẹ̀lú wa, a ó lọ ra oúnjẹ wá fún ọ.

Jẹ́nẹ́sísì 43

Jẹ́nẹ́sísì 43:3-5