Jẹ́nẹ́sísì 43:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A mú àwọn ọkùnrin náà jókòó lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀, bí wọ́n ṣe dàgbà sí, láti orí ẹ̀gbọ́n pátapáta dé orí èyí tí ó kéré pátapáta, wọ́n sì ń wo ara wọn tìyanu tìyanu.

Jẹ́nẹ́sísì 43

Jẹ́nẹ́sísì 43:29-34