Jẹ́nẹ́sísì 43:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn rẹ̀ sì fà sí i gidigidi nígbà tí ó rí arákùnrin rẹ̀, nítorí náà Jósẹ́fù yára jáde láti wá ibi tí ó ti le sunkún. Ó lọ sí iyàrá rẹ̀, ó sì sunkún níbẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 43

Jẹ́nẹ́sísì 43:28-31