Jẹ́nẹ́sísì 43:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà wọ́n lọ bá ìránṣẹ́ Jósẹ́fù, wọ́n sì ba sọ̀rọ̀ ní ẹnu ọ̀nà à bá wọlé ilé náà.

Jẹ́nẹ́sísì 43

Jẹ́nẹ́sísì 43:10-23