Jẹ́nẹ́sísì 43:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí Ọlọ́run alágbára jẹ́ kí ẹ rí àánú gbà lọ́dọ̀ ọkùnrin náà kí ó ba à le jẹ́ kí arákùnrin yín tí ó wà lọhun-un àti Bẹ́ńjámínì padà wá pẹ̀lú yín. Ní tèmi, bí mo bá pàdánù àwọn ọmọ mi, n ó sọ̀fọ̀ wọn náà ni.”

Jẹ́nẹ́sísì 43

Jẹ́nẹ́sísì 43:7-23