Jẹ́nẹ́sísì 43:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ìlọ́po owó méjì ni kí ẹ mú lọ́wọ́, nítorí ẹ gbọdọ̀ dá owó tí ẹ bá lẹ́nu àpò yín padà. Bóyá ẹnìkan ló sèèsì fi ṣíbẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 43

Jẹ́nẹ́sísì 43:3-22