Jẹ́nẹ́sísì 42:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó yípadà kúrò lọ́dọ̀ wọn, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní sunkún. Ó sì tún yí padà sí wọn, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní sọ̀rọ̀. Ó mú Símónì kúrò láàrin wọn, ó sì dè é ní ojú wọn.

Jẹ́nẹ́sísì 42

Jẹ́nẹ́sísì 42:18-26