Jẹ́nẹ́sísì 41:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni olórí agbọ́tí wí fún Fáráò pé, “Lónìí ni mo rántí àìṣedéédé mi.

Jẹ́nẹ́sísì 41

Jẹ́nẹ́sísì 41:1-19