Jẹ́nẹ́sísì 41:54 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọdún méje ìyàn sì bẹ̀rẹ̀, bí Jósẹ́fù ti wí gan-an. Ìyàn sì mú ní gbogbo ilẹ̀ tó kù, ṣùgbọ́n oúnjẹ wà ní gbogbo ilẹ̀ Éjíbítì.

Jẹ́nẹ́sísì 41

Jẹ́nẹ́sísì 41:48-57