Jẹ́nẹ́sísì 41:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ ọgbọ̀n ọdún (30) ni Jósẹ́fù nígbà tí ó wọ iṣẹ́ Fáráò ọba Éjíbítì. Jósẹ́fù sì jáde kúrò níwájú Fáráò, ó sì ṣe ìbẹ̀wò káàkiri gbogbo ilẹ̀ Éjíbítì

Jẹ́nẹ́sísì 41

Jẹ́nẹ́sísì 41:41-48