Jẹ́nẹ́sísì 41:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fáráò sì bọ́ òrùka èdìdì ọwọ́ rẹ̀, ó sì fi wọ Jósẹ́fù ó wọ̀ ọ́ ní aṣọ ọ̀gbọ̀ dáradára, ó sì fi ẹ̀gbà tí ó dára sí i lọ́rùn.

Jẹ́nẹ́sísì 41

Jẹ́nẹ́sísì 41:33-50