Jẹ́nẹ́sísì 41:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ìwọ yóò ṣe àkóso ààfin mi gbogbo àwọn ènìyàn gbọdọ̀ tẹríba fún àṣẹ ẹ̀ rẹ. Ìtẹ́ mi nìkan ni èmi yóò fi jù ọ́ lọ.”

Jẹ́nẹ́sísì 41

Jẹ́nẹ́sísì 41:32-46